1. Sam 26:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si mọ̀ ohùn Dafidi, o si wipe, Ohùn rẹ li eyi bi, Dafidi ọmọ mi? Dafidi si wipe, Ohùn mi ni, oluwa mi, ọba.

1. Sam 26

1. Sam 26:12-22