1. Sam 24:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gẹgẹ bi owe igba atijọ ti wi, Ìwabuburu a ma ti ọdọ awọn enia buburu jade wá; ṣugbọn ọwọ́ mi kì yio si lara rẹ.

1. Sam 24

1. Sam 24:5-16