1. Sam 19:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si sa, o si bọ, o si tọ Samueli wá ni Rama, o si rò fun u gbogbo eyi ti Saulu ṣe si i. On ati Samueli si lọ, nwọn si ngbe Naoti.

1. Sam 19

1. Sam 19:15-22