1. Sam 18:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi a si ma lọ si ibikibi ti Saulu rán a, a ma huwa ọlọgbọ́n: Saulu si fi i jẹ olori ogun, o si dara loju gbogbo awọn enia, ati pẹlupẹlu loju awọn iranṣẹ Saulu.

1. Sam 18

1. Sam 18:1-9