1. Sam 17:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si wi fun Dafidi pe, Iwọ kò le tọ Filistini yi lọ lati ba a jà: nitoripe ọdọmọde ni iwọ, on si jẹ jagunjagun lati igba ewe rẹ̀ wá.

1. Sam 17

1. Sam 17:25-35