1. Sam 14:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi nwọn ba wi fun wa pe, Ẹ duro titi awa o fi tọ̀ nyin wá; awa o si duro, awa kì yio si goke tọ̀ wọn lọ.

1. Sam 14

1. Sam 14:5-11