1. Pet 2:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati pẹlu, okuta idigbolu, on apata ikọsẹ̀. Nitori nwọn kọsẹ nipa ṣiṣe aigbọran si ọrọ na ninu eyiti a gbé yàn wọn si pẹlu.

1. Pet 2

1. Pet 2:4-13