1. Pet 2:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni, nigbati a kẹgan rẹ̀, ti kò si pada kẹgan; nigbati o jìya, ti kò si kilọ; ṣugbọn o fi ọ̀ran rẹ̀ le ẹniti nṣe idajọ ododo lọwọ:

1. Pet 2

1. Pet 2:22-25