1. Kro 8:19-24 Yorùbá Bibeli (YCE)

19. Ati Jakimu, ati Sikri, ati Sabdi,

20. Ati Elienai, ati Siltai, ati Elieli,

21. Ati Adaiah, ati Beraiah, ati Ṣimrati ni awọn ọmọ Ṣimhi;

22. Ati Iṣpani, ati Eberi, ati Elieli,

23. Ati Abdoni, ati Sikri, ati Hanani,

24. Ati Hananiah, ati Elamu, ati Antotiah,

1. Kro 8