1. Kro 8:15-20 Yorùbá Bibeli (YCE)

15. Ati Sebadiah, ati Aradi, ati Aderi,

16. Ati Mikaeli, ati Ispa, ati Joha, ni awọn ọmọ Beria;

17. Ati Sobadiah, ati Meṣullamu, ati Heseki, ati Heberi.

18. Iṣmeri pẹlu, ati Jeslia, ati Jobabu, ni awọn ọmọ Elpaali.

19. Ati Jakimu, ati Sikri, ati Sabdi,

20. Ati Elienai, ati Siltai, ati Elieli,

1. Kro 8