1. Kro 8:13-20 Yorùbá Bibeli (YCE)

13. Beria pẹlu, ati Ṣema, ti nwọn iṣe olori awọn baba awọn ara Ajaloni, awọn ti o le awọn ara Gati kuro.

14. Ati Ahio, Ṣaṣaki, Jerimotu,

15. Ati Sebadiah, ati Aradi, ati Aderi,

16. Ati Mikaeli, ati Ispa, ati Joha, ni awọn ọmọ Beria;

17. Ati Sobadiah, ati Meṣullamu, ati Heseki, ati Heberi.

18. Iṣmeri pẹlu, ati Jeslia, ati Jobabu, ni awọn ọmọ Elpaali.

19. Ati Jakimu, ati Sikri, ati Sabdi,

20. Ati Elienai, ati Siltai, ati Elieli,

1. Kro 8