13. Beria pẹlu, ati Ṣema, ti nwọn iṣe olori awọn baba awọn ara Ajaloni, awọn ti o le awọn ara Gati kuro.
14. Ati Ahio, Ṣaṣaki, Jerimotu,
15. Ati Sebadiah, ati Aradi, ati Aderi,
16. Ati Mikaeli, ati Ispa, ati Joha, ni awọn ọmọ Beria;
17. Ati Sobadiah, ati Meṣullamu, ati Heseki, ati Heberi.