1. Kro 8:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. BENJAMINI si bi Bela, akọbi rẹ̀, Aṣbeli ekeji, ati Ahara ẹkẹta,

2. Noha ẹkẹrin, ati Rafa ẹkarun.

3. Awọn ọmọ Bela ni Addari, ati Gera, ati Abihudi,

1. Kro 8