Ati awọn ọmọ Hananiah; Pelatiah, ati Jesaiah: awọn ọmọ Refaiah, awọn ọmọ Arnani, awọn ọmọ Obadiah, awọn ọmọ Ṣekaniah.