1. Kro 3:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹkẹta, Absalomu ọmọ Maaka ọmọbinrin Talmai ọba Gesuri; ẹkẹrin, Adonijah ọmọ Haggiti.

1. Kro 3

1. Kro 3:1-8