1. Kro 26:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NITI ipin awọn adena: niti awọn ọmọ Kosa ni Meṣelemiah ọmọ Kore, ninu awọn ọmọ Asafu.

2. Ati awọn ọmọ Meṣelemiah ni Sekariah akọbi, Jediaeli ekeji, Sebadiah ẹkẹta, Jatnieli ẹkẹrin,

3. Elamu ẹkarun, Johanani ẹkẹfa, Elioenai ekeje.

1. Kro 26