1. Kro 2:18-20 Yorùbá Bibeli (YCE)

18. Kalebu ọmọ Hesroni si bi ọmọ lati ọdọ Asuba aya rẹ̀, ati lati ọdọ Jeriotu: awọn ọmọ rẹ̀ ni wọnyi; Jeṣeri, ati Ṣohabu, ati Ardoni.

19. Nigbati Asuba kú, Kalebu mu Efrati, ẹniti o bi Huri fun u.

20. Huri si bi Uru, Uru si bi Besaleeli.

1. Kro 2