1. Kro 15:4-6 Yorùbá Bibeli (YCE)

4. Dafidi si pè awọn ọmọ Aaroni, ati awọn ọmọ Lefi jọ.

5. Ninu awọn ọmọ Kohati; Urieli olori, ati awọn arakunrin rẹ̀ ọgọfa:

6. Ninu awọn ọmọ Merari; Asaiah olori, ati awọn arakunrin rẹ̀ igba o le ogun:

1. Kro 15