1. Kro 11:45-47 Yorùbá Bibeli (YCE)

45. Jediaeli ọmọ Simri, ati Joha arakunrin rẹ̀ ara Tisi,

46. Elieli ara Mahafi, ati Jeribai, ati Joṣafia, awọn ọmọ Elnaamu, ati Tima ara Moabu.

47. Elieli, ati Obedi, ati Jasieli ara Mesobah.

1. Kro 11