26. Serugu, Nahori, Tera,
27. Abramu; on na ni Abrahamu,
28. Awọn ọmọ Abrahamu; Isaaki, ati Iṣmaeli.
29. Wọnyi ni iran wọn: akọbi Iṣmaeli, Nebaioti; ati Kedari, ati Adbeeli, ati Mibsamu,
30. Miṣma, ati Duma, Massa, Hadadi, ati Tema,
31. Jeturi, Nafiṣi, ati Kedema. Wọnyi li awọn ọmọ Iṣmaeli.