1. Kro 1:24-29 Yorùbá Bibeli (YCE)

24. Ṣemu, Arfaksadi, Ṣela,

25. Eberi, Pelegi, Reu,

26. Serugu, Nahori, Tera,

27. Abramu; on na ni Abrahamu,

28. Awọn ọmọ Abrahamu; Isaaki, ati Iṣmaeli.

29. Wọnyi ni iran wọn: akọbi Iṣmaeli, Nebaioti; ati Kedari, ati Adbeeli, ati Mibsamu,

1. Kro 1