1. Kro 1:21-25 Yorùbá Bibeli (YCE)

21. Ati Hadoramu, ati Usali, ati Dikla,

22. Ati Ebali, ati Abimaeli, ati Ṣeba,

23. Ati Ofiri, ati Hafila, ati Jobabu. Gbogbo wọnyi li awọn ọmọ Joktani.

24. Ṣemu, Arfaksadi, Ṣela,

25. Eberi, Pelegi, Reu,

1. Kro 1