1. Kor 6:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ mã sá fun àgbere. Gbogbo ẹ̀ṣẹ ti enia ndá o wà lode ara; ṣugbọn ẹniti o nṣe àgbere nṣẹ̀ si ara on tikararẹ̀.

1. Kor 6

1. Kor 6:8-20