1. Kor 16:23-24 Yorùbá Bibeli (YCE) Õre-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa ki o pẹlu nyin. Ifẹ mi wà pẹlu gbogbo nyin ninu Kristi Jesu. Amin.