1. Kor 1:29-31 Yorùbá Bibeli (YCE)

29. Ki o máṣe si ẹlẹran-ara ti yio ṣogo niwaju rẹ̀.

30. Ṣugbọn nipasẹ rẹ̀ li ẹnyin wà ninu Kristi Jesu, ẹniti Ọlọrun fi ṣe ọgbọ́n, ati ododo, ati isọdimimọ́, ati idande fun wa:

31. Pe, gẹgẹ bi a ti kọ ọ, Ẹniti o ba nṣogo, ki o mã ṣogo ninu Oluwa.

1. Kor 1