1. A. Ọba 6:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ile na ti Solomoni ọba kọ́ fun Oluwa, gigun rẹ̀ jẹ ọgọta igbọnwọ, ibú rẹ̀, ogun igbọnwọ, ati giga rẹ̀, ọgbọn igbọnwọ.

1. A. Ọba 6

1. A. Ọba 6:1-3