1. A. Ọba 4:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE) SOLOMONI ọba si jẹ ọba lori gbogbo Israeli. Awọn wọnyi ni awọn ijoye ti o ni; Asariah, ọmọ Sadoku