1. A. Ọba 22:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ỌDUN mẹta si rekọja laisi ogun lãrin Siria ati lãrin Israeli.

2. O si ṣe li ọdun kẹta, Jehoṣafati, ọba Juda sọkalẹ tọ ọba Israeli wá.

1. A. Ọba 22