1. A. Ọba 1:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sadoku alufa, ati Natani woli, ati Benaiah, ọmọ Jehoiada, ati awọn ara Kereti ati Peleti si sọkalẹ, nwọn si mu ki Solomoni ki o gùn ibãka Dafidi ọba, nwọn si mu u wá si Gihoni,

1. A. Ọba 1

1. A. Ọba 1:37-41