Hos 7:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Igberaga Israeli si njẹri si i li oju rẹ̀; nwọn kò si yipadà si Oluwa Ọlọrun wọn, bẹ̃ni fun gbogbo eyi nwọn kò si wá a.

Hos 7

Hos 7:2-16