Hab 3:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

A ṣi ọrun rẹ̀ silẹ patapata, gẹgẹ bi ibura awọn ẹ̀ya, ani ọ̀rọ rẹ. Iwọ ti fi odò là ilẹ aiye.

Hab 3

Hab 3:1-13