Gẹn 47:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati emi ba sùn pẹlu awọn baba mi, iwọ o gbe mi jade ni Egipti, ki o si sin mi ni iboji wọn. On si wipe, Emi o ṣe bi iwọ ti wi.

Gẹn 47

Gẹn 47:29-31