Gẹn 37:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li awọn oniṣòwo ara Midiani nkọja lọ; nwọn si fà a, nwọn si yọ Josefu jade ninu ihò, nwọn si tà Josefu li ogún owo fadaka: nwọn si mú Josefu lọ si Egipti.

Gẹn 37

Gẹn 37:23-35