Gẹn 30:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi ọpá ti o bó lelẹ niwaju awọn agbo-ẹran li oju àgbará, ni ibi ọkọ̀ imumi, nigbati awọn agbo-ẹran wá mu omi, ki nwọn ki o le yún nigbati nwọn ba wá mumi.

Gẹn 30

Gẹn 30:35-43