Gẹn 20:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ABRAHAMU si ṣí lati ibẹ̀ lọ si ilẹ ìha gusù, o si joko li agbedemeji Kadeṣi on Ṣuri; o si ṣe atipo ni Gerari.

Gẹn 20

Gẹn 20:1-2