Gẹn 2:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si busi ijọ́ keje, o si yà a si mimọ́; nitori pe, ninu rẹ̀ li o simi kuro ninu iṣẹ rẹ̀ gbogbo ti o ti bẹ̀rẹ si iṣe.

Gẹn 2

Gẹn 2:1-4