Gẹn 19:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ki nwọn ki o to dubulẹ, awọn ọkunrin ara ilu na, awọn ọkunrin Sodomu, nwọn yi ile na ká, ati àgba ati ewe, gbogbo enia lati ori igun mẹrẹrin wá.

Gẹn 19

Gẹn 19:2-13