Gẹn 19:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AWỌN Angeli meji si wá si Sodomu li aṣalẹ; Loti si joko li ẹnu-bode Sodomu: bi Loti si ti ri wọn, o dide lati pade wọn: o si dojubolẹ;

Gẹn 19

Gẹn 19:1-7