Gẹn 11:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, bi nwọn ti nrìn lati ìha ìla-õrùn lọ, ti nwọn ri pẹtẹlẹ kan ni ilẹ Ṣinari; nwọn si tẹdo sibẹ̀.

Gẹn 11

Gẹn 11:1-4