Gẹn 10:16-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

16. Ati awọn ara Jebusi, ati awọn ara Amori, ati awọn ara Girgaṣi,

17. Ati awọn ara Hiffi, ati awọn ara Arki, ati awọn ara Sini,

18. Ati awọn ara Arfadi, ati awọn ara Semari, ati awọn ara Hamati; lẹhin eyini ni idile awọn ara Kenaani tàn kalẹ.

Gẹn 10