Gal 3:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹniti o fun nyin li Ẹmí na, ti o si ṣe iṣẹ-agbara larin nyin, nipa iṣẹ ofin li o fi nṣe e bi, tabi nipa igbọran igbagbọ́?

Gal 3

Gal 3:3-12