Gal 1:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti o fi on tikalarẹ̀ fun ẹ̀ṣẹ wa, ki o le gbà wa kuro ninu aiye buburu isisiyi, gẹgẹ bi ifẹ Ọlọrun ati Baba wa:

Gal 1

Gal 1:1-9