Esr 7:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NJẸ lẹhin nkan wọnyi, ni ijọba Artasasta ọba Persia, Esra ọmọ Seraiah, ọmọ Asariah, ọmọ Hilkiah,

2. Ọmọ Ṣallumu, ọmọ Sadoku, ọmọ Ahitubu,

Esr 7