Esr 2:20-25 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. Awọn ọmọ Gibbari, marundilọgọrun.

21. Awọn ọmọ Betlehemu, mẹtalelọgọfa.

22. Awọn enia Netofa, mẹrindilọgọta.

23. Awọn enia Anatotu, mejidilãdọje.

24. Awọn ọmọ Asmafeti, mejilelogoji.

25. Awọn ọmọ Kirjat-arimu, Kefira ati Beeroti ọtadilẹgbẹrin o le mẹta.

Esr 2