O si mu mi jade wá si agbalá ode, o si mu mi kọja ni igun mẹrẹrin agbalá na; si kiyesi i, ni olukuluku igun agbalá na ni agbala kan gbe wà.