Esek 45:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Efa ati bati yio jẹ ìwọn kanna, ki bati ba le gbà ìdamẹwa homeri, ati efa idamẹwa homeri: iwọ̀n rẹ̀ yio jẹ gẹgẹ bi ti homeri.

Esek 45

Esek 45:7-19