Esek 44:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si kọ́ awọn enia mi ni iyàtọ ti o wà lãrin mimọ́ ati ailọ̀wọ, nwọn o si mu wọn mọ̀ eyiti o wà lãrin aimọ́ ati mimọ́.

Esek 44

Esek 44:21-28