Esek 41:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kerubu ati igi ọpẹ li a si fi ṣe e, igi ọpẹ kan si mbẹ lãrin kerubu ati kerubu: kerubu kọkan si ni oju meji;

Esek 41

Esek 41:17-24