Esek 4:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mu awo irin kan, ki o si gbe e duro bi odi irin lãrin rẹ ati ilu na: ki o si kọju si i, a o si dótì i, iwọ o si dótì i. Eyi o jẹ àmi si ile Israeli.

Esek 4

Esek 4:1-10