Esek 38:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si goke wá si awọn enia mi Israeli, bi awọsanma lati bò ilẹ; yio si ṣe nikẹhin ọjọ, emi o si mu ọ dojukọ ilẹ mi, ki awọn orilẹ-ède ki o le mọ̀ mi, nigbati a o yà mi si mimọ́ ninu rẹ, niwaju wọn, iwọ Gogu.

Esek 38

Esek 38:14-18